ORIN OPE by Daniel Ebhomien, Victus Eze and Justina Ebhomien — Lyrics

Daniel Ebhomien, Victus Eze and Justina Ebhomien Yoruba Offertory Hymns Hymns Marian Hymns Staff & Solfa notation

Full Lyrics

Ọpẹ, ọpẹ, iyin lo yẹ fun o, Baba to da wa si d'oni o, ọpẹ ni fun O o Baba gb'ọrẹ wa o. Ọpẹ iyin lo yẹ fun o, Baba to da wa si d'oni o, ọpẹ ni fun O o Baba gb'ọrẹ wa o. Gbaa lowo mi o Baba, jẹ ki ọrẹ wa dodo rẹ, ọrẹ bi ti Abẹli o, Baba gb'ọrẹ wa o. Ọpẹ, ọpẹ o iyin lo yẹ fun o, Baba to da wa si d'oni o, ọpẹ ni fun O o Baba gb'ọrẹ wa o. A wi ma yẹhun, Ọlọrun gbogbo agbaye, Ọmọ Maria, Mimọ Olugbala wa, Arugbo ọjọ, agba ni la gba tan o, Oyigiyigi, Oluwa, Baba gb'ọrẹ wa o. Ọpẹ, ọpẹ o, iyin lo yẹ fun o, Baba to da wa si d'oni o, ọpẹ ni fun O o Baba gb'ọrẹ wa o. Ẹ wa s'ọpẹ fun Baba wa, Ọlọrun ẹyin eniyan mi, Ẹ m'ọrẹ t'o j'oju wa, Ọrẹ t'o layọ, t'o l'ere, ẹ wa o, ẹ wa s'ọpẹ fun O, Baba Ọrun, Baba wa o, Baba o, Baba gb'ọrẹ wa, Baba o, Baba gb'ọrẹ wa, Baba o, Baba gb'ọrẹ wa, Baba o, Baba gb'ọrẹ wa, Jọwọ Baba gbaa lowo wa.

Download the sheet music

ORIN OPE

ORIN OPE

By Daniel Ebhomien, Victu...
Staff & Solfa
Yoruba
5 pages
1 Downloads
Offertory Hymns Hymns Marian Hymns
0 0

More lyrics you may want