OORE-OFE RE by Nworie Collins Ifejika — Lyrics

Nworie Collins Ifejika Yoruba FILM 2025 FILM Songs Lenten Hymns Prayer Hymns Staff & Solfa notation

Full Lyrics

[CHORUS] Jésù mi, iwó kú lórí àgbélébùú nitori èsémi, sibèsibè, ese mi n mu o je'ro ra. Nitori ifékùfé ara mo n súbú sinú èsè ni gbàgbogbo. Ah! Ijebi nlá nlá ni! Mo kàánú fún gbogbo irorare, Olúwa. Mo kàánú fún gbogbo àisedédé ni! Mo bèbè fún ooreòfé re, kin lè yi'wà padà si rere, kin lè hùwà rere. Opò igbà ni mo ti pinu láti fi àwon èsè mi silè. Opò igbà ni mo n subú pada sinú èsè kan náà. Ah! Olorun, nigbàkúùgbà ti mo bá d'ésè ni mo n pàdá nù ooreòfé re ijebi èsè ti dè mi mólè! [TENOR SOLO] Olúwa, njé iwo yóò je ki n sègbé sinú èsè, nitori kòsi Olùrànwó fún mi? Ani ninú òpò ooreòfé re? Ah! Jesu mi! Nipa ijiyà re lóri Agbélébùú Nipa irora ti o faradà Nipa ikú re lóri Agbélébùú Nipa iségun re lóri ikú Nipa iségun re lóri èsè Nipa iségun re lóri iná àinipeèkun mo jéwó wipé tire ni mo jé iwó jé tèmi. Ah! Olúwa! [CHORUS] Ah... Gbami ninú àánú re. Gbami ninú àánú re. Gbami ninú àánú re. Gbami ninú àánú re. Gbami ninú àánú re. Gbami ninú àánú re. Gbami ninú àánú re. Gbami ninú àánú re. Ah! Mo kaanu fun gbogbo ese mi.

Download the sheet music

OORE-OFE RE

OORE-OFE RE

By Nworie Collins Ifejika
Staff & Solfa
Yoruba
6 pages
0 Downloads
FILM 2025 FILM Songs Lenten Hymns Prayer Hymns
0 0

More lyrics you may want