OORE-OFE RE - Choir Script PDF Thumbnail
Preview
0 0
0 downloads
Added Jul 22, 2026
Uploaded By: Choir PDFs
Format: Staff & Solfa
Language: Yoruba
Pages: 6 pages

OORE-OFE RE by Nworie Collins Ifejika — Lyrics

[CHORUS] Jésù mi, iwó kú lórí àgbélébùú nitori èsémi, sibèsibè, ese mi n mu o je'ro ra. Nitori ifékùfé ara mo n súbú sinú èsè ni gbàgbogbo. Ah! Ijebi nlá nlá ni! Mo kàánú fún gbogbo irorare, Olúwa. Mo kàánú fún gbogbo àisedédé ni! Mo bèbè fún ooreòfé re, kin lè yi'wà padà si rere, kin lè hùwà rere. Opò igbà ni mo ti pinu láti fi àwon èsè mi silè. Opò igbà ni mo n subú pada sinú èsè kan náà. Ah! Olorun, nigbàkúùgbà ti mo bá d'ésè ni mo n pàdá nù ooreòfé re ijebi èsè ti dè mi mólè! [TENOR SOLO] Olúwa, njé iwo yóò je ki n sègbé sinú èsè, nitori kòsi Olùrànwó fún mi? Ani ninú òpò ooreòfé re? Ah! Jesu mi! Nipa ijiyà re lóri Agbélébùú
Read full lyrics

About OORE-OFE RE

"Oore-Ofe Re" (Your Grace) is a deeply moving Yoruba choral piece that speaks directly to the human struggle with sin and the overwhelming need for God's mercy. The lyrics carry the voice of a repentant soul reflecting on Christ's sacrifice on the cross, confessing how often we resolve to leave our sins behind only to fall back into them. It is a song of raw honesty, capturing that familiar spiritual battle and the heavy guilt that ties us down.

As the piece unfolds, a poignant Tenor Solo rises above the choir, pleading with the Lord and recalling the agony, death, and ultimate victory of Christ over sin and eternal fire. Beneath this solo, the choir provides a gentle, continuous prayer: "Gbami ninú àánú re" (Save me by your mercy). This interplay makes it an exceptional choice for Lenten reflections, penitential services, or any moment of deep prayer and adoration in the parish. The soaring melodies and heartfelt words invite both the singers and the congregation to lean entirely on the grace of God.