Káàbọ? by Adeboye Banjo / Victus Eze / Ehimare Asuelinmen — Lyrics

Adeboye Banjo / Victus Eze / Ehimare Asuelinmen Yoruba FILM 2017 Entrance songs Celebrations Christmas Hymns Solfa notation

Full Lyrics

A ti ri irawọ ogo, idunnu si ti kun aye A ti ri irawọ ogo, idunnu si ti kun aye Ayọ, ayọ, ayọ, idunnu si ti kun aye Ayọ, ayọ, ayọ! awọn angẹli n kọrin; Ayọ, ayọ, ayọ, ayọ, ayọ, ayọ. Awa naa n kọrin. Káàbọ̀ Ọba awọriọba Káàbọ̀ Olugbala araye. Imọlẹ ayeraye; Káàbọ̀ Ọba awọriọba, Imọlẹ ayeraye; Káàbọ̀ Ọba, káàbọ̀. O de! Alade ogo ti wa s'aye, O de! Tiyanu, tibukun l'o de o, O de! araye ẹ wa k'a lọ s'iba fun; O ti wa lati sọ wa d'ọtun, Ọba wa, alaafia l'o mu de o, Atẹrẹrẹ kariaye o, O de o! araye ẹ wa k'a lọ s'iba fun; Imanueli O, káàbọ̀ Ọba awọriọba O de o! araye ẹ wa k'a lọ s'iba fun. Imanueli O, káàbọ̀ Ọba awọriọba O de! araye ẹ wa k'a lọ s'iba fun. Ọba wa, káàbọ̀ Ọba, káàbọ̀. Káàbọ̀ Olugbala araye, káàbọ̀ Imọlẹ ayeraye. Káàbọ̀ Ọba, káàbọ̀ Imọlẹ ayeraye. Káàbọ̀ Ọba, káàbọ̀ Imọlẹ ayeraye. BARITONE SOLO Ninu ẹsẹ ni awa ti n gbe, kosi ẹda kankan to wa gba wa, afi Ọm'ọba ayeraye; CHORUS Jesu Kristi, Mẹsaya, ti de! Ọba titi aye, Ehm! Ọba mimọ, Ọba mimọ, Kabiyesi. Ọba nla awa, Ọba wa ni, Ọba ogo, Ọba ogo, Ọba nla awa, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Oun l'Ọba! TENOR SOLO Ọba asọrọ m'asẹ m'asẹ. afasẹ m'aye, afasẹ m'ọrun, Ọniye mimọ. káàbọ̀! CHORUS Onisẹ mimọ o. Ọba adani magbagbe ẹni, amọ'ni de'nu ni Ọba, abi sooro kandu kandu. Ọl'ọkan mimọ o. káàbọ̀! Afunni masiregun l'o de. Ẹku ile'n juba Rẹ, Ẹku ọkọ n yin O, talo le sin O to, Ọba titi aye, Kabiyesi. Ọba nla awa, Ọba mimọ, Ọba mimọ, Ọba ogo, Ọba ogo, Ọba nla awa, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Oun l'Ọba! OPTIONAL SOLO Ọba adani ni ifẹ ẹni. Ọba to wa lati ku fun ẹni, CHORUS Ọba titi aye, Kabiyesi. Ọba mimọ, Ọba mimọ, Ọba ogo, Ọba ogo, Ọba nla awa, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Oun l'Ọba! apeni k'ẹni ni o, Ọba nla awa, Ọba wa ni, Ọba nla awa, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Oun l'Ọba! Ẹku ile'n juba Rẹ, Ọba iba, iba o! Ọba nla awa, Ọba wa ni, Kabiyesi. Ọba ogo, Ọba ogo, Ọba nla awa, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Ọba wa ni, Oun l'Ọba! Káàbọ̀. Imọlẹ ayeraye. Káàbọ̀. Imọlẹ ayeraye.

Download the sheet music

Káàbọ?

Káàbọ?

By Adeboye Banjo / Victus...
Solfa
Yoruba
3 pages
12 Downloads
FILM 2017 Entrance songs Celebrations Christmas Hymns
0 0

More lyrics you may want