Káàbọ? - Choir Script PDF Thumbnail
Preview
0 0
12 downloads
Added Sep 28, 2025
Uploaded By: Choir PDFs
Format: Solfa
Language: Yoruba
Pages: 3 pages

Káàbọ? by Adeboye Banjo / Victus Eze / Ehimare Asuelinmen — Lyrics

A ti ri irawọ ogo, idunnu si ti kun aye A ti ri irawọ ogo, idunnu si ti kun aye Ayọ, ayọ, ayọ, idunnu si ti kun aye Ayọ, ayọ, ayọ! awọn angẹli n kọrin; Ayọ, ayọ, ayọ, ayọ, ayọ, ayọ. Awa naa n kọrin. Káàbọ̀ Ọba awọriọba Káàbọ̀ Olugbala araye. Imọlẹ ayeraye; Káàbọ̀ Ọba awọriọba, Imọlẹ ayeraye; Káàbọ̀ Ọba, káàbọ̀. O de! Alade ogo ti wa s'aye, O de! Tiyanu, tibukun l'o de o, O de! araye ẹ wa k'a lọ s'iba fun; O ti wa lati sọ wa d'ọtun, Ọba wa, alaafia l'o mu de o, Atẹrẹrẹ kariaye o, O de o! araye ẹ wa k'a lọ s'iba fun; Imanueli O, káàbọ̀ Ọba awọriọba O de o! araye ẹ wa k'a lọ s'iba fun. Imanueli O, káàbọ̀ Ọba awọriọba O de! araye ẹ wa k'a lọ s'iba fun. Ọba wa, káàbọ̀ Ọba, káàbọ̀. Káàbọ̀ Olugbala araye, káàbọ̀ Imọlẹ ayeraye. Káàbọ̀ Ọba, káàbọ̀ Imọlẹ ayeraye. Káàbọ̀ Ọba, káàbọ̀ Imọlẹ ayeraye. BARITONE SOLO Ninu ẹsẹ ni awa ti n gbe, kosi ẹda kankan to wa gba wa, afi Ọm'ọba ayeraye;
Read full lyrics

About Káàbọ?

"Káàbọ̀" is a majestic Yoruba choral piece that rings with the pure joy of welcoming the Savior. Right from the opening lines—declaring that we have seen the star of glory and that joy has filled the earth—the song sets a scene of profound celebration. It captures the excitement of the angels singing and invites the congregation to join in welcoming the eternal King. With its references to the guiding star and the arrival of Emmanuel, it is a magnificent choice for Christmas and Epiphany Masses, though its grand scale makes it just as fitting for any major feast day where a triumphant entrance is needed.

The arrangement is beautifully structured to build momentum, moving from a full-choir declaration of welcome into expressive solo verses for baritone and tenor. These solos reflect on our need for salvation and praise the unfailing nature of God, before the choir sweeps back in with resounding titles of praise—calling Him the great King, the holy King, and the eternal light. For a choir, mastering the rhythmic vitality and the rich, layered harmonies of this piece brings a wonderful energy to the loft. It is a song that truly lifts the spirit, drawing everyone in the church into a shared, jubilant welcome for the Messiah.