EYIN L'OGO YE by Cornelius Ogor — Lyrics

Cornelius Ogor Yoruba Offertory Hymns Holy Trinity Hymns Solfa notation

Full Lyrics

Ko ma s'eni keji to feran mi bi olufe okan mi, to fi ite ogo re sile o wa damilare. Iwo nikan soso la ma sin ni gbogbo aiye wa o, Oba nla. Wa giga giga, Eyin l'ogo ye, Eyin l'ogo ye. Eyin ni yin ye, Oba awon 'ba, a yin tan Eledumare. Ibere ati opin, Eyin l'ogo ye, Eyin ni yin ye. Mee le sai dupe ore re si mi, Olu orun o. A wole sai dupe ore re si wa, ore re to boju aiye. Alapinle to so aiye ro, Erujeje l'eli o kun pupo, abanigbani lan saya, Eyin Arugbo ojo. Oba ko ma ti ka leyin, Ajijo dodo inrawo Omo Mary. Oba to to korin kese, korin kese, korin kese, korin ke se. Ah! Eyin l'ogo ye. Ibere ati opin, A wole fun o, Baba Baba Baba, Eyin l'ogo ye. Baba, Omo, Emi mi, Eyin ni yin ye.

Download the sheet music

EYIN L'OGO YE

EYIN L'OGO YE

By Cornelius Ogor
Solfa
Yoruba
2 pages
8 Downloads
Offertory Hymns Holy Trinity Hymns
0 0

More lyrics you may want