Full Lyrics
Ayọ ọrun sọkalẹ
Ẹbun ọfẹ sọkalẹ
Alejò rere de
Iṣẹ ọwọ rẹ ko di bajẹ
Eledumare
Titi la o ma yin o
Onibu ọrẹ
A bi Jesu fun wa
Oni l'ọjọ t'a bi Olugbala wa
Keresimesi ọdun ayọ de o
Ara ẹ wa
A bi Jesu fun wa
Keresimesi de
Ara ẹ wa
Keresimesi de, Keresimesi de
A bi Olugbala kan fun wa
Kan fun wa ni ilu Bẹtlihẹm
Ẹni ti yio j'ọba
Ayeraye
Awa si wa lati mu ẹbun f'ọba
Ọdun ti de
Keresimesi ọdun de
Ọdun owo, ọdun ọlọmọ
Edumare jẹ ka s'ọpọ ẹ
Makulumu ke
Ma a jo f'Ọlọrun mi
Ọpọn mi le
O fun mi l'ayọ mo yege
Keresimesi tun s'oju emi wa
Ọdun ọdun yii a yabo
Ọdun ọdun yii a mirin gindin
Paregede la o ye
Ọdun titun to mbọ lọna
A bọ yun le
Baba jẹ o s'oju emi wa
A bi ti bi ti rẹ
Emi tọn s'owo
Ma a rere ọja
Ẹni gbọ mọ dani
K'asan ma pa wọn
Baba jẹ o s'oju emi wa
K'ọmọ lamini mọ wa
Aimasi ko l'ọnda mu ẹda
Ogun aye kan ko le bami lẹru mọ
Emi ti sọ wipe t'Oluwa l'aṣẹ
K'ori kokin hun k'ori apata
K'Oluwa koso wa de le o
Kare re o
Ọja ka fẹ rẹ o ko de le
Ọba wa eh, Ọba wa
Ọba t'a bi s'aiye