Full Lyrics
VERSE 1
Yọ ṣẹṣẹ kọrin s'Oluwa
Mu ọrẹ wa fun Ọba Ọlọla
SOLO
Gbohun soke
CHORUS
Kọrin s'Oluwa
Kọrin s'Oluwa
Kọrin s'Oluwa Ọba Ọlọla
VERSE 2
F'ọyaya kọrin s'Oluwa
Mu ọrẹ wa fun Ọba Ọlọla
VERSE 3
F'irẹlẹ kọrin s'Oluwa
Mu ọrẹ wa fun Ọba Ọlọla
VERSE 4
F'ẹbun atata tọrẹ f'Oluwa
Fun ọrẹ nla Ọba Ọlọla
VERSE 5
Ṣaṣaro ore t'Oluwa ṣe
Ninu aye rẹ, ko dupẹ
VERSE 6
Ara ọtọ lore t'Oluwa ṣe
Ninu aye rẹ ko dupẹ