Full Lyrics
VERSE 1
Ẹ jẹ ka jọ yọ ka fi jó sí o,
A bi Olugbala kan fun wa.
Ẹyin onigbagbọ ẹ ho ẹ yọ
A bi Jesu, Olugbala.
Let us now rejoice and hail this great morn:
For the world a mighty Saviour born;
Glorious King, for ever be Thou adored,
Holy Jesus, Redeemer Lord!
REFRAIN
Awa ki o, Ọba mimọ,
Awa juba fun ọ Ọba ogo.
Awa, Awa ki o Ọba mimọ,
Awa juba rẹ Ọba ogo.
Ẹyin onigbagbọ ẹ ho ẹ yọ
A bi Jesu Olugbala.
We salute Thee, new born, holy King!
Pray, accept the loyal tribute we bring.
We salute Thee, holy King!
Pray, accept the tribute we bring;
Glorious King, for ever be Thou adored;
Blessed Jesus, our Saviour Lord!
VERSE 2 (SOPRANI)
Ijọba yoo wa ni ejika rẹ,
Oun ni Ọba Awọn Ọba,
Oun yoo jọba titi Aiye o,
Alade alafia.
King of kings is He, and Lord of lords,
Ever will he reign, Prince of peace,
On his shoulder will the government be:
And His kingdom'll never cease!
VERSE 3 (TENORS & BASSES)
Awọn Amoye mẹta Igbani,
Wọn ri Irawo kan didan,
Irawo yi ni wọn tọ lẹhin,
lati juba fun Ọba tuntun,
Wọn wi pe:
Three wise men came from a land so far,
Guided by a bright shining star,
In a manger the baby they saw:
To him they gave all the gifts they bore, praising Him: