Full Lyrics
REFRAIN
Tewo gbebo wa
Baba wa tewo gbebo wa
Baba Olodumare
Iwo la waru bosi o,
Tewo gbebo wa.
Laye laye
Tewo gbebo wa
Baba wa tewo gbebo wa
Baba Olodumare
Iwo la waru bosi o,
Tewo gbebo wa.
VERSE 1
Baba Egbewa Papa awon la waru bo fun o Tewogbebo wa
Awon aropo Papa awon la waru bo fun o Tewogbebo wa
Gbagbo Kristia ni awon la waru bo fun o Tewogbebo wa
VERSE 2
Awa pelu Maria Iwo la waru bosi o Tewogbebo wa
Awa pelu Josefu Iwo la waru bosi o Tewogbebo wa
Awa pelu Peteru Iwo la waru bosi o Tewogbebo wa
Baba Olodumare Iwo la waru bosii Tewogbebo wa