Full Lyrics
CHORUS
Tẹwọ gbẹbọ wa,
Baba tẹwọ gbẹbọ wa.
1ST TIME
Tẹwọ gbẹbọ wa,
Laiye, Baba wa tẹwọ gbẹbọ wa.
REFRAIN
Tẹwọ gbẹbọ, laiye,
Laiye, Baba wa tẹwọ gbẹbọ wa,
Tẹwọ gbẹbọ wa.
VERSE 1
Baba ẹgbẹ wa papa,
Oun lawa rubọ fun O,
Awọn arọpọ papa,
Awọn lawa rubọ fun O,
Gbogbo Kristiani,
Awọn lawa rubọ fun,
Tẹwọ gbẹbọ wa.
VERSE 2
Awa pẹlu Maria,
Ẹyin lawa rubọ si O,
Awa pẹlu Josẹfu,
Ẹyin lawa rubọ si O,
Baba Olodumare,
Ẹyin lawa rubọ si,
Tẹwọ gbẹbọ wa.