TẸWỌ GB'ẸBỌ WA by Egbe Akorin Dahomey, Matthew Okojie — Lyrics

Egbe Akorin Dahomey, Matthew Okojie Yoruba Offertory Hymns Eucharistic songs Hymns Staff & Solfa notation

Full Lyrics

[CHORUS] Tẹwọ gb'ẹbọ wa, Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa. Baba Olodumare, Iwọ la wa rubọ si o, tẹwọ gb'ẹbọ wa. Laye Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ; laye, laye Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa. Ah Baba Olodumare, Iwọ la wa rubọ si o, tẹwọ gb'ẹbọ wa. [VERSE 1] Baba ẹgbẹ wa Papa, Iwọ la wa rubọ fun o, tẹwọ gb'ẹbọ wa. Gbogbo Kristani, Awọn la wa rubọ fun, tẹwọ gb'ẹbọ wa. Awọn arọpo Papa, Awọn la wa rubọ fun o, tẹwọ gb'ẹbọ wa. Gbogbo Kristani, Awọn la wa rubọ fun, tẹwọ gb'ẹbọ wa. [VERSE 2] Awọn pẹlu Maria, Iwọ la wa rubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. Baba Olodumare, Iwọ la wa rubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. Awọn pẹlu Josẹfu, Iwọ la wa rubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. Baba Olodumare, Iwọ la wa rubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. Awọn pẹlu Peteru, Iwọ la wa rubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. Baba Olodumare, Iwọ la wa rubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. [VERSE 3] Ko yi pada s'ara rẹ Jesu. Ko yi pada s'ẹjẹ rẹ Jesu. Ọti wini pẹl'akara. Ọti wini pẹl'akara.

Download the sheet music

TẸWỌ GB'ẸBỌ WA

TẸWỌ GB'ẸBỌ WA

By Egbe Akorin Dahomey, M...
Staff & Solfa
Yoruba
1 page
0 Downloads
Offertory Hymns Eucharistic songs Hymns
0 0

More lyrics you may want