TẸWỌ GB'ẸBỌ WA by Ajase Choir, Dahomey / Adidi Franklin 'O — Lyrics

Ajase Choir, Dahomey / Adidi Franklin 'O Yoruba Offertory Hymns Hymns Solfa notation

Full Lyrics

CHORUS Tẹwọ gb'ẹbọ wa Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa Baba Olodumare, Iwọ l'a wa rubọ si o Tẹwọ gb'ẹbọ wa REFRAIN L'aye, Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ l'aye L'aye Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa Baba Olodumare, Iwọ l'a wa rubọ si o Tẹwọ gb'ẹbọ wa VERSE 1 Baba ẹgbẹ wa papa, awọn l'a wa rubọ fun o Tẹwọ gb'ẹbọ wa Awọn arepọ papa, awọn l'a wa rubọ fun o Tẹwọ gb'ẹbọ wa Gbogbo Kristiani, awọn l'a wa rubọ fun Tẹwọ gb'ẹbọ wa VERSE 2 Awa pẹlu Maria, Iwọ l'a wa rubọ si o Tẹwọ gb'ẹbọ wa Awa pẹlu Josefu, Iwọ l'a wa rubọ si o Tẹwọ gb'ẹbọ wa Awa pẹlu Peteru, Iwọ l'a wa rubọ si Tẹwọ gb'ẹbọ wa Baba Olodumare, Iwọ l'a wa rubọ si Tẹwọ gb'ẹbọ wa VERSE 3 K'o yi pada s'ara Rẹ Jesu K'o yi pada s'ẹjẹ Rẹ Jesu K'o ma yi pada s'ara Rẹ Jesu K'o ma yi pada s'ẹjẹ Rẹ Jesu

Download the sheet music

TẸWỌ GB'ẸBỌ WA

TẸWỌ GB'ẸBỌ WA

By Ajase Choir, Dahomey /...
Solfa
Yoruba
1 page
2 Downloads
Offertory Hymns Hymns
0 0

More lyrics you may want