Full Lyrics
CHORUS
Tẹwọ gbẹbọ wa,
Baba wa tẹwọ gbẹbọ wa,
Baba Olodumare,
Ẹyin la wa rubọ si o.
REFRAIN
Tẹwọ gbẹbọ wa,
Laiye, Baba wa tẹwọ gbẹbọ wa,
Laiye, Baba wa tẹwọ gbẹbọ wa.
VERSE 1
Baba ẹgbẹ wa papa,
Oun la wa rubọ fun o,
Awọn arọpọ papa,
Awọn la wa rubọ fun o,
Gbogbo kristiani,
Awọn la wa rubọ fun,
Tẹwọ gbẹbọ wa.
VERSE 2
Awa pẹlu Maria,
Ẹyin la wa rubọ si o,
Awa pẹlu Peteru,
Ẹyin la wa rubọ si o.
Baba Olodumare,
Ẹyin la wa rubọ si,
Tẹwọ gbẹbọ wa.