Full Lyrics
INTRO
Tẹwọ gb'ẹbọ wa.
Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa.
Baba Olodumare, iwọ la wa rubọ si o.
CHORUS
Laye Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ laye, laye Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa. Ah!
Olodumare, iwọ la wa rubọ si o, tẹwọ gb'ẹbọ wa.
VERSE 1
Ẹgbẹ wa papa la wa rubọ o, tẹwọ gb'ẹbọ wa.
Awọn aro papa papa ni la wa rubọ o, tẹwọ gb'ẹbọ wa.
VERSE 2
Gbogbo 'Kristi a ni, iwọ la wa rubọ fun, tẹwọ gb'ẹbọ wa.
Gbogbo 'Kristi a ni, iwọ la wa rubọ fun, tẹwọ gb'ẹbọ wa.
VERSE 3
Awọn pẹlu, iwọ la wa rubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa.
Baba Olodumare, iwọ la wa rubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa.
CONSECRATION
K'o yipada s'ara rẹ Jesu.
K'o yipada s'ẹjẹ rẹ Jesu.