Full Lyrics
CHORUS
Tẹwọ gbẹbọ wa Baba wa
Tẹwọ gbẹbọ wa Baba Olodumare
Iwọ la wa rubọ si o
Tẹwọ gbẹbọ wa laye Baba wa
Tẹwọ gbẹbọ laye laye Baba wa
Tẹwọ gbẹbọ wa Baba Olodumare
Iwọ la wa rubọ si o
Tẹwọ gbẹbọ wa
VERSE 1
Baba ẹgbẹ wa pọ
Awọn ara pọ la
Gbogbo kristiani
Awọn la wa rubọ fun o
VERSE 2
Awa pẹlu Maria
Awa pẹlu Josefu
Awa pẹlu Peteru
Iwọ la wa rubọ si o
VERSE 3
Koyi pada s'ara rẹ Jesu
Koyi pada s'ẹjẹ rẹ Jesu
O waini pẹl'akara
Ko ma yi pada s'ara rẹ Jesu