TEWO GBEBO WA by Matthew Osagie — Lyrics

Matthew Osagie Yoruba Offertory Hymns Hymns Solfa notation

Full Lyrics

VERSE 1 Tẹwọ gb'ẹbọ wa, Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa, Baba Olodumare, iwọ la wa nrubọ si o. VERSE 2 Laye Baba wa tẹwọ gb'ẹbọ wa, Laye Olodumare, iwọ la wa nrubọ si o. CHORUS Olodumare, iwọ la wa nrubọ si o, Tẹwọ gb'ẹbọ wa. VERSE 3 Ẹgbẹ wa ra pa ohun la wa nrubọ si o, tẹwọ gb'ẹbọ wa, Baba Olodumare, iwọ la wa nrubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. VERSE 4 Awa naa ra popa pa ohun la wa nrubọ si o, tẹwọ gb'ẹbọ wa, Baba Olodumare, iwọ la wa nrubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. VERSE 5 Gbogbo kristiani, iwọ la wa nrubọ si o, tẹwọ gb'ẹbọ wa, Baba Olodumare, iwọ la wa nrubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. VERSE 6 Awọn pẹlu, iwọ la wa nrubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa, Baba Olodumare, iwọ la wa nrubọ si, tẹwọ gb'ẹbọ wa. CODA Kò yẹ pada s'ẹhin rẹ Jesu. Kò yi pada s'ẹhin rẹ Jesu. Kò ma yi pada s'ẹhin rẹ Jesu.

Download the sheet music

TEWO GBEBO WA

TEWO GBEBO WA

By Matthew Osagie
Solfa
Yoruba
1 page
2 Downloads
Offertory Hymns Hymns
0 0

More lyrics you may want