Full Lyrics
[SECTION A]
Jésù mi, ìwọ ku lórí Agbelebuu nítorí èṣè mi,
síbèsíbè, èṣè mi ń mú ẹ jè'rora:
ara Mo ńṣubú sínú èṣè nígbà gbogbo.
Ah! ìnjẹbí ńlá ńlá nì!
Mo kàáànú fún gbogbo àìṣèdédé.
Mo kàáànú fún gbogbo àìṣèdédé.
Mo bẹbẹ fún ooreòfé rẹ,
kí n lè yí'wa padà sí rere,
kí n lé hùwa rere.
[SECTION B]
Ọpọ ìgbà ni mo ti pinnu láti fi àwọn èṣè mi sílè.
Ọpọ ìgbà ni mo ń ṣubú padà sínú èṣè kan náà,
Ah! Ọlórun, nigbakúùgbà ti mo bá d'éṣè ni mo ń padánù ooreòfé rẹ.
Darìjì mi, Oluwa!
ìnjẹbí èṣè ti dè mí mọ lẹ!
Mo kàáànú...
[SOLO ENTRY (Male)Expressivo]
Oluwa, ǹ jé ìwọ yóò jẹkí n ṣègbé sínú èṣè,
nítorí kò sí Olùrànwọ fún mi?
Àní ninu ooreòfé rẹ?
Ah! Jesu mi!
[TUTTI ENTRY]
Nípa 'jìya rẹ lórí Agbélébùú
Nípa ìrora ti o farada
Nípa ikú rẹ lórí Agbélébùú
Nípa ìṣégun rẹ lórí ikú
Nípa ìṣégun rẹ lórí iná ànipekun
Mo jéwó wípé èmi rẹ
Mo jé ìwọ jé tè mi.
Gbàmi nínú àánú rẹ
Ah! Oluwa! Mo kàáànú fún gbogbo èṣè mi.