Full Lyrics
[Verse 1]
Oni l'ọjọ pe, Oni l'ọjọ pe,
Edumare, Olupese, Ọba mimọ, O seun.
Awa dupẹ, Olu Ọrun, awa dẹ, a dẹ O.
Iwọ l'o jẹ k'oni s'oju wa O,
Awa dupẹ, Baba Ọrun awa dẹ.
[Chorus]
A dupẹ Jesu, a dupẹ Baba,
O se Baba Ọrun O, a dupẹ O.
[Verse 2]
Awa dupẹ, awa dẹ O,
Awa dupẹ, a yin Baba l'oke.
Ẹni to da wa si d'oni O.
Awa dupẹ, awa dupẹ, a yin Ọba.
[Verse 3]
K'o'rin alleluya, ẹyin ọmọ igbala O.
K'o'rin alleluya si Baba Edumare duma.
Gbogbo ẹyin ẹniyan ẹ wa ba wa dupẹ.
A n ni ọla kun ọla, a n ni iyi kun iyi.
Adẹ ori wa ko si daru.
Ẹyi na t'on ti wa.