Ona ope mi opo by Aderemi Olaide — Lyrics

Aderemi Olaide Yoruba Offertory Hymns Hymns Solfa notation

Full Lyrics

CHORUS Ọna ọpẹ mi o pọ O pọ jọjọ A wa juba niwaju rẹ Ki ọpẹ ko sẹ, tẹwọ gba A wa siwaju rẹ Lati wa fi ọpẹ to yẹ fun Ọ Gba lọwọ wa Ki ibukun ko jẹ ti wa VERSE 1 A dupẹ, wa gbọ pẹ wa A wa juba fun Ọ o A wa wọle fun Ọ o A tun de loni Gbọ pẹ wa VERSE 2 Ẹ jẹ ka lọ siwaju Oluwa Ẹ jẹ ka lọ, ẹ ma ṣe bẹru Ẹ jẹ ka lọ, ka lọ yin logo Ẹ jẹ ka lọ nitori pe Oun lo da gbogbo aye To gbe ilẹ kalẹ lori omi To ni ilẹ ati ẹkun rẹ Ko wa yọ ninu ewu wẹlu O pa wa mọ ninu ibi gbogbo Fun eyi ati awọn to mọ Gbọ pẹ wa

Download the sheet music

Ona ope mi opo

Ona ope mi opo

By Aderemi Olaide
Solfa
Yoruba
2 pages
2 Downloads
Offertory Hymns Hymns
0 0

More lyrics you may want