Full Lyrics
CHORUS
Oluwa gb'ore wa,
Oluwa gb'ore wa,
Oluwa gb'ore wa k'io ya si mimo o.
Oluwa gb'ore wa,
Oluwa gb'ore wa k'io ya si mimo o.
VERSE 1
Baba Oloore gb'ore wa,
Yonu si abun wa,
Oyigiyi si Baba wa,
Jowo dariji wa o.
VERSE 2
Oun t'e se fun wa o,
Oun t'e se fun wa o,
Oun t'e se fun wa o,
Iyanu l'o je fun wa.
Owo ti e fun wa o,
Omo ti e fun wa o,
Ibukun ti e fun wa o,
Iyanu l'o je fun wa.