Full Lyrics
Ogo ni fun O o mesaya o baba,
ogo ni fun O pe O gba lati wa,
Ogo ni fun O o mesaya o baba,
Emmanuel ka bo O ma ma seun.
A ma wo le fun oba wa,
a f'ori bale o,
A ma wo le fun oba wa,
a wa f'ori bale o.
Ogo f'Olorun loke orun
Ati ni aye alafia,
Ife inu rere si eniyan titi lai.
Ogo ni fun O o mesaya o baba,
ogo ni fun O pe O gba lati wa,
Ogo ni fun O o mesaya o baba,
Emmanuel ka bo O ma ma seun.