Full Lyrics Ọdọ Aguntan Ọlọrun Iwọ t'o nko ẹṣẹ aye lọ Ṣaanu fun wa, ṣaanu fun wa, ṣaanu fun wa Ọdọ Aguntan Ọlọrun Iwọ t'o nko ẹṣẹ aye lọ Fun wa ni alafia.