Full Lyrics
CHORUS
Mimọ, mimọ l'Oluwa O,
Awọn Angẹli n'yin;
Mimọ, mimọ l'Oluwa O.
VERSE 1
Ọrun ati aye yin O,
Wọn kọrin mimọ l'Oluwa!
Mimọ, mimọ l'Oluwa O.
VERSE 2
Ibukun ni f'ẹni t'ọn bọ wa
L'orukọ Oluwa O;
Ẹ pe mimọ l'Oluwa.
HOSANNA
Hosana l'olu Ọrun o!
Hosana fun Baba wa!
Hosana! Hosana!
Ba mi pe Mimọ l'Oluwa!
Mimọ O, mimọ O, mimọ!