Full Lyrics
Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi,
Ọba pipe, Ọba ogo ni Ọ o.
Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi,
Olugbala ni Ọ Oluwa wa.
Olutunu ni Ọ Ọlọrun mi,
Olutunu, Olutunu,
Olutunu ni Ọ Ọlọrun mi,
Olutunu ni Messiah.
Ọba ni Ọ, Ọba ni Ọ,
Oluwa wa, Oluwa.
Ninu ipọnju O kọ mi yọ ninu ewu.
Gbani gbani to'ngba ni ni Messiah,
Gbani gbani O, gbani gbani ni.
Gbani gbani O, Ọba pipe ni,
Ọba mimọ, Ọba titi,
Messiah Ọba pipe ni,
Ọba lae lae, Ọba ni O.