Full Lyrics
SOLO
Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi,
Ọba pipe, Ọba ogo ni Ọ o.
Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi,
Olugbala ni Ọ Oluwa wa.
CHORUS
Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi,
Ọba pipe, Ọba ogo ni Ọ o.
Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi,
Olugbala ni Ọ Oluwa wa.
Olutunu ni Ọ Ọlọrun mi,
Olutunu, Olutunu,
Olutunu ni Ọ Ọlọrun mi,
Olutunu ni Messiah.
Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi,
Ọba pipe, Ọba ogo ni Ọ o.
Ọba ni Ọ, Ọba ni Ọ,
Oluwa wa, Oluwa wa.
SOLO
Ninu ipọnju O ko mi yọ,
Ninu ewu.
Baba mi ye, Ohun l'ọ gba mi,
Gbani gbani ni Messiah.
CHORUS
Gbani gbani t'o ngba ni ni O,
Gbani gbani O, gbani gbani ni.
Gbani gbani O, Ọba pipe ni,
Gbani gbani O, Ọba pipe ni.
Gbani gbani O, Ọba pipe ni,
Ọba mimọ, Ọba titi,
Ọba laelae, Ọba ni O.