Messiah, Baba mi by Ayo Ogunranti Jnr — Lyrics

Ayo Ogunranti Jnr Yoruba Celebrations Recessional / Dismissal Hymns Hymns Solfa notation

Full Lyrics

Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi, Ọba pipe, Ọba Ogo ni O O. Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi, Olugbala ni O Oluwa wa. Olutunu ni O Ọlọrun mi, Olutunu Oluwa ni Messiah. Olutunu ni O Ọlọrun mi, Olutunu ni Messiah. Messiah, Baba mi, Messiah, Ọrẹ mi, Ọba pipe, Ọba Ogo ni O O. Ọba ni Ọba ni O, Oluwa wa, Oluwa wa. Ninu ipọnju O ko mi yọ ninu ewu. Baba mi ye. Ohun lo gba mi gbani gbani to'ngba ni ni Messiah, gbani gbani to'ngba ni ni O, Ọba gbani gbani O, Ọba pipe ni, Ọba pipe ni, Ọba pipe ni, gbani gbani O, Ọba pipe ni; Ọba mimọ, Ọba titi, ni, Messiah ni Ọba laelae, Ọba O.

Download the sheet music

Messiah, Baba mi

Messiah, Baba mi

By Ayo Ogunranti Jnr
Solfa
Yoruba
2 pages
4 Downloads
Celebrations Recessional / Dismissal Hymns Hymns
0 0

More lyrics you may want