Full Lyrics
CHORUS
Ma f'ope fun O Baba mimo
Aleluya mo dupe
E ko mi yo ninu gbogbo iji
O fun mi l'ayo ma jo
Ma fi jo f'ayo f'Oluwa wa
Aleluya mo dupe
Ore kanka ore gbangba
O seun O
VERSE 1
Ninu ewu gbogbo o ko mi yo
Iku ibi gbogbo o mu mi ye
K'ibi tun je mibi to se ope
Ma k'orin ayo, ayo s'Oluwa
Baba emi mo're
Opo lo ti ku O
Opo lo wole won
Emi wa l'aye
VERSE 2
E ba mi yo Oluwa lo so mi da l'ayo
E ba mi yo
Oluwa ti segun fun mi
Imo ota ti d'ofo l'ori mi
E ba mi yo
Ayo, ore gbangba
O seun O