Keresimesi Ti De (Christmas is Here) by Obioha Ogbonna and Banjo Adeboye — Lyrics

Obioha Ogbonna and Banjo Adeboye Yoruba Christmas Celebrations Solfa notation

Full Lyrics

[CHORUS] Adupẹ o Baba, A dupẹ o Jesu Adupẹ o Baba, A dupẹ o Jesu Keresimesi Kristi, Keresimesi Kristi Awaju ba fun ọ Jesu Keresimesi Kristi, Keresimesi Kristi Olugbala Kristi o ti de o Ati ri irawọ ogo Idunnu si ti ku aye Ayọ kun ọrun o A bi Jesu Imanueli Awọn Angeli n k'ọrin Ayọ Keresimesi ti de [MODULATION] Kajuba fun Ọba, ọba ti de Ẹ kọrin Aleluya, olugbala ti de Ọba awọn ọba Jesu, Alade ogo ti de Kajuba fun Ọba, ọba ti de Ẹ kọrin Aleluya, ba awọn ọba Jesu Kristi Alade ogo ti de Kajuba fun Ọba, ọba ti de Ẹ kọrin Aleluya, Olugbala wa kaabọ [CHOIR OSTINATO] Parararam Parararam, Parararam Olugbalawa ti de Parararam, Parararam Olugbala wa Kaabọ Parararam, Parararam Oo ẹse o Ẹmi mimọ Parararam, Parararam Olugbala wa Kaabọ Oo ṣe Jesu o, ṣe Jesu Oluwa, Oluwa, Oluwa, Oluwa Kaabọ o Ọbani, Ọbani, Ọbani, Ọbani [SOPRANO] Wa a n wa a n wa a n wa Ẹmi mimọ ni irawo a ti Rin a ti rin a ti rin rin rin Irawọ lo gbewa de A gbagbọ ninu Mesaya Adari gbogbo ẹda Ni Bẹtẹlẹhẹmu lati A ti ri irawo rẹ o O sin dan yanyan ni Ibukun ni fun Mariya iya ọba igbala Ọpẹ ọpẹ ni fun Josefu to duroti imọlẹ wa Nigbugbe ẹran lati ri ọba ogo Keresimesi ti de Olugbala wa de Irapada awa ti de

Download the sheet music

Keresimesi Ti De (Christmas is Here)

Keresimesi Ti De (Christmas is Here)

By Obioha Ogbonna and Ban...
Solfa
Yoruba
2 pages
18 Downloads
Christmas Celebrations
0 0

More lyrics you may want