Full Lyrics
CHORUS
Ẹ ṣe Jesu, fun abo rẹ o
A gbe o ga o, Olowogbogboro
Olowogbogboro, mo dansaki rẹ, ọba iye
A gbe o ga o, Olowogbogboro
VERSE 1
O fun mi l'ayọ, ẹ ṣe gan
VERSE 2
O gbe mi leke, ẹ ṣe gan
VERSE 3
O fun mi l'ọla, alafia
VERSE 4
O fun mi l'owo, mo dupẹ o
VERSE 5
Ibukun aye rẹ, l'aye mi o pọ jojo o