THREE YORUBA SONGS: I. ÌYÁ by Ayo Bankole — Lyrics

Ayo Bankole Yoruba Mothers song Concert Non-Liturgical / Special Choir Arrangements Classicals Staff notation

Full Lyrics

Ìyá Ìyá Ìyá l'olùfẹ́ jùlọ ní kékéré, Ìyá Nígbà tí mo sùn òun l'ó ṣọ́ mi, Nígbàtí mo jí òun l'ó gbé mi; Nígbà t'ébi ńpa mi òun l'ó bọ́ mi, òun l'ó bọ́ mi, òun l'ó bọ́ mi. Kò s'ẹ́ni t'ó fẹ́ràn mi t'ó mọ àini mi t'ó sì lè pèsè fún mi bí Ìyá mi, Ìyá mi, Ìyá mi. K'ò s'ẹ́ni t'ó fẹ́ràn mi, k'ò s'ẹ́ni t'ó fẹ́ràn mi, k'ò s'ẹ́ni t'ó t'ó t'ó fẹ́ràn mi k'ò s'ẹ́ni t'ó fẹ́ràn mi t'ó mọ àini mi k'Ólúwa k'ó gbè ọ́ o.

Download the sheet music

THREE YORUBA SONGS: I. ÌYÁ

THREE YORUBA SONGS: I. ÌYÁ

By Ayo Bankole
Staff
Yoruba
4 pages
11 Downloads
Mothers song Concert Non-Liturgical / Special Choir Arrangements Classicals
0 0

More lyrics you may want