Full Lyrics
Ìbà...
Òkùnkùn pim pim, atẹ́gùn fẹ́ẹ́rẹ́fẹ́, ìwọ la dáhùn akéhùn.
Ìmọ́lẹ̀ yanyan, iná laulau, ìwọ la dáhùn akéhùn.
Gbogbo nkan tẹ́ dá o, a wa lè fún.
Gbogbo nkan tẹ́ ṣe, a wa lè ṣe fún baba.
Kí lati rí kí la mọ̀, baba?
Ẹyin l'ọba àwọn ọba,
Alágbára ará! Alágbára ará ẹ!
Ìbà o! Ìbà f'Olu ọ̀run!
Ìbà o! Ìbà f'Olu ọ̀run. Ìbà f'Olu ọ̀run.
Ìbà! Kò sí! Rárá! Ìbà! Ìbà! Ìbà!
Ìbà! Ìbà! Ìbà! Ìbà!
Gbogbo nkan tẹ́ dá o, a wa lè fún.
Gbogbo nkan tẹ́ ṣe, a wa lè ṣe fún baba.
Kí lati rí kí la mọ̀, baba?
Ẹyin l'ọba àwọn ọba,
Alágbára ará! Alágbára ará ẹ!
Ìbà o! Ìbà f'Olu ọ̀run!
Ìbà o! Ìbà f'Olu ọ̀run. Ìbà f'Olu ọ̀run.
TENOR SOLO
A júbà Rẹ!
Olùmọ̀rànkàn ìbà rẹ, ìbà!
Ọlọ́run Ọlọ́run Ọlọ́run aléfẹ́ropẹ́dárùn.
Ọba títí! Ọba tòtó! Ọba wa tójú ìgbà lailai.
Aláṣẹ ayé ìbà rẹ! Aláṣẹ ọ̀run ìbà rẹ!
Olùmọ̀rànkàn ìbà rẹ, ìbà!
Ìbà o! Ìbà! Ìbà! Ìbà! Ìbà!
O Ìbà f'Olu ọ̀run, ìbà! Ìbà o!
Ìbà f'Olu ọ̀run. F'Olu ọ̀run.
Ìbà! Ìbà!
Ìbà! Ìbà f'Olu ọ̀run.
TENOR
Ọba ayérayé, ìbà Rẹ! Ìbà Rẹ!