Full Lyrics
CHORUS
Gbọrẹ wa o, gbọrẹ wa o, Eledumare
Gbọrẹ wa Baba l'oke, gbọrẹ wa
Fun ore ẹ f'ere ninu aiye wa, Baba adupẹ o
Gb'ọrẹ ti a muwa, Eledumare
VERSE 1
Ọpẹ iyin, ogo l'a muwa siwaju rẹ Baba wa
Ilu l'orin l'amu wa
Baba l'oke, Baba l'oke
L'ọwọ gb'ọpẹ wa
L'ọwọ gb'ọpẹ wa, Baba l'oke
Gb'ọrẹ ti a muwa, Eledumare
VERSE 2
O ṣe fun wa wipe ninu ohun k'ohun ki a ma dupẹ
Ohun ti ba ṣẹlẹ fun rera fun wa
Adupẹ, adupẹ, Baba adupẹ o
Gb'ọrẹ ti a muwa, Eledumare
VERSE 3
Mo mọ ri ore Baba o
Iwọ ọrẹ mi ye o
Sunmọ bi wa gbọ o
Sunmọ bi wa gbọ Baba
Ṣe rere fun wa
Sunmọ bi wa gbọ
Ere rẹ fun wa
Sunmọ bi wa gbọ Baba
Ṣe rere fun wa
Sunmọ bi wa gbọ
Awa dupẹ