Full Lyrics
[CHORUS]
Gbẹbọ wa, dakun Baba Mimọ o, gbẹbọ wa,
Olodumare.
Gbẹbọ wa dakun Baba o, gbẹbọ wa,
Olodumare.
Gbẹbọ wa dakun Baba o, gbẹbọ wa,
Olodumare.
Baba o, gbẹbọ wa.
Ẹbọ! Mimọ! Ẹbọ! Pipé!
Ẹbọ mimọ, ẹbọ pipé,
Ẹbọ! Iye o,
Ẹbọ mimọ, ẹbọ pipé,
Ẹbọ iye l'a ru si o.
Ah, ẹbọ iye l'a ru si o.
Gbẹbọ wa, Baba o, gbẹbọ wa.
Gbẹbọ wa, Baba o, gbẹbọ wa.
[VERSE 1]
Akara l'a mu wa,
Ọrẹ awa ọmọ rẹ,
Ọti l'a mu wa l'a ti inu eso t'o fun wa,
Ah, jọwọ ma sai gbẹbọ wa,
Baba dakun gbẹbọ wa,
Gbẹbọ wa, Baba o, gbẹbọ wa.
Baba dakun gbẹbọ wa,
Gbẹbọ wa, Baba o, gbẹbọ wa.
Baba dakun gbẹbọ wa,
Gbẹbọ wa o.
[VERSE 2]
Gbọrẹ, gbọrẹ,
Olodumare, Oluwa, jọwọ
Jọwọ wa gbẹrẹ ti a mu wa o,
Jọwọ wa gbẹbọ wa o.
Oluwa, jọwọ
Gbẹbọ, gbẹbọ,
Jọwọ wa gbẹbọ ti a ru si o.
Jọwọ wa gbẹbọ wa o.
Olodumare.
Baba Olore, ye dakun
Jọwọ wa gbẹbọ wa o.
Jọwọ wa gbẹbọ wa o.