Gbẹbọ Wa, Dakun by Ademola Adeosun — Lyrics

Ademola Adeosun Yoruba FILM 2009 Offertory Hymns Hymns Solfa notation

Full Lyrics

[CHORUS] Gbẹbọ wa, dakun Baba Mimọ O, gbẹbọ wa, Olodumare Gbẹbọ wa dakun Baba O, gbẹbọ wa, Olodumare Gbẹbọ wa dakun Baba O, gbẹbọ wa, Ẹbọ! Mimọ! Ẹbọ! Pipe! Ẹbọ! Iye O, ẹbọ mimọ, ẹbọ pipe, ẹbọ iye l'a ru si O Baba O, gbẹbọ wa. [VERSE 1] Akara l'a muwa, ọrẹ awu ọmọ Rẹ, Ọti l'a muwa l'ati inu eso t'o fun wa, Jọwọ ma sai gbẹbọ wa, Baba dakun gbẹbọ wa, gbẹbọ wa, Baba O, gbẹbọ wa. [VERSE 2] Olodumare, Oluwa, jọre, Jọwọ wa gb'ọrẹ ti a mu wa O, Jọwọ wa gb'ọrẹ wa O. Jọwọ wa gb'ọrẹ ti a mu si O. Jọwọ wa gb'ọrẹ wa O. Olodumare, Baba Ol'ore, Ye dakun Jọwọ wa gb'ọrẹ wa O. Jọwọ wa gb'ọrẹ wa O.

Download the sheet music

Gbẹbọ Wa, Dakun

Gbẹbọ Wa, Dakun

By Ademola Adeosun
Solfa
Yoruba
3 pages
18 Downloads
FILM 2009 Offertory Hymns Hymns
0 0

More lyrics you may want