Full Lyrics
CHORUS
Gbẹbọ wa, dakun Baba Mimọ O, gbẹbọ wa,
Gbẹbọ wa dakun Baba O, gbẹbọ wa,
Olodumare,
Gbẹbọ wa dakun,
Baba O, gbẹbọ wa.
Ẹbọ! Mimọ! Ẹbọ! Pipe!
Ẹbọ! Iye O Ẹbọ pipe, Ẹbọ iye la ru si o
Baba O, gbẹbọ wa.
VERSE 1
Akara l'a muwa
Ọrẹ awu ọmọ Rẹ
Ọti l'a muwa
l'a tinu ẹsọ t'o fun wa,
Baba dakun gbẹbọ wa,
gbẹbọ wa,
Baba O, gbẹbọ wa.
VERSE 2
Oluwa, jare
jọwọ wo gb'ẹrẹ t'a mu wa O.
Jọwọ wa gbẹbọ wa
Oluwa, jare
jọwọ wa gbẹbọ wa
Jọwọ wa gbẹbọ t'a ru si o
Jọwọ wa gbẹbọ wa
Olodumare,
Baba Olore, Ye dakun
Jọwọ wa gbẹbọ wa O.
Jọwọ wa gbẹbọ wa O.
Olodumare.