ORIN ỌPẸ́ by Chenko — Lyrics

Chenko Yoruba Folk songs Entrance songs Offertory Hymns Celebrations Hymns Solfa notation

Full Lyrics

[ANDANTE] Kabiyesi o Baba e se o, e se o Kabiyesi Baba wa e se o Baba wa e se, awa ki o, Kabiyesi Ọba mimọ o se Kabiyesi wa gbọ́ pẹ, Baba e se Kabiyesi gbọ́ pẹ se Kabiyesi wa gbọ́ pẹ fun gbogbo iyi t'e se l'aye wa Baba o, e se eh! Kabiyesi o gbọ́ pẹ, se Kabiyesi o gbọ́ pẹ, Baba e se Kabiyesi gbọ́ pẹ Eh! Baba e se o, Baba e se o, Baba e se o, Ọba mimọ e se o, Ọba mimọ e se o, Ọba mimọ e se [SOPRANO SOLI & CHORUS] Eh! Baba e se o, Baba Baba Baba e se o, Baba e se o e se Baba e se o Ọba mimọ e se o, Ọba mimọ e se o, Ọba mimọ e se Baba e seun o, Baba wa e se, Baba Baba Baba e se, Baba e se o e se Baba e se o e se Ọba mimọ e se o, Ọba mimọ e se o, Ọba mimọ e se fun'l bukun rẹ o, eh Baba e se, gbọ́ gboun t'e se fun wa ti ga ju lọ, Baba Baba e se o e se Baba e se o Ọba mimọ e se o, Ọba mimọ e se o, Ọba mimọ e se Eh! Baba e se o, Baba Baba Baba e se o, Baba e se o e se Baba e se o Ọba mimọ e se o, Ọba mimọ e se o [ALLEGRO 6/8] Baba wa gbọ́ pẹ, Baba wa gbọ́ pẹ, Baba wa gbọ́ pẹ Baba Eledumare o, Baba wa gbọ́ pẹ Ọpẹ o, Baba wa gbọ́ pẹ [SOPRANO SOLI] Awa dupẹ Baba, awa dupẹ Baba, awa dupẹ Baba Eledumare Baba, Mẹtalọkan Baba, Oyigiyigi Baba, awa dupẹ o Baba Olusan agutan Baba, Alakọse nla Baba, Iyi yẹ o Baba Awa dupẹ Baba, awa dupẹ Baba, awa dupẹ Baba, Ogo yẹ o Baba [CHORUS] Ẹ ba mi ki Arugbo ọjọ, eh! Arugbo ọjọ, Arugbo ọjọ Arugbo ọjọ, ẹ ba mi ki Baba wa, Baba wa, Baba wa eh Baba wa, eh Baba wa, ẹ ba mi ki Baba wa, Baba wa, Baba wa Ọba mimọ, Ọba mimọ, eh Ọba mimọ, Ọba mimọ, Ọba mimọ, ẹ ba mi ki Ọba mimọ, Ọba mimọ, Ọba mimọ [OSTINATO] E se Baba, e se Baba, e se Baba, e se Baba, e se Baba, e se Baba, e se Baba, e se Baba [TENOR SOLO] Eh Ọba iye Kabiyesi o, Ọba nla nla nla nla nla gbọ́ pẹ Wa jọwọ awimayẹhun Ọba Oloore, Ẹyin l'ọba to guju lọ o Iyin yẹ fun o Baba, Ẹmi mimọ Mẹtalọkan eh Oniṣẹ iyanu Ọba awo'ọba gbọ́ gboun t'ẹ se fun wa l'aiye o o pọ o e se [ALLEGRETTO 4/4] A dupẹ o a dupẹ Ọba nla nla nla gbọ́ pẹ o a dupẹ E se e se Baba a dupẹ o a dupẹ O a dupẹ o a dupẹ, ẹ ba wa s'ọpẹ o Angẹli ọrun a dupẹ o a dupẹ Amin Amin Amin Amin Amin Amin Amin Amin Amin o yẹ o yẹ o amin o

Download the sheet music

ORIN ỌPẸ́

ORIN ỌPẸ́

By Chenko
Solfa
Yoruba
5 pages
4 Downloads
Folk songs Entrance songs Offertory Hymns Celebrations Hymns
0 0

More lyrics you may want