Eyin L'ogo Ye by Cornelius Ogar — Lyrics

Cornelius Ogar Yoruba Offertory Hymns Recessional / Dismissal Hymns Holy Trinity Hymns Solfa notation

Full Lyrics

[Chorus] Kò ma s'ẹni kẹ to fẹran mi bi olufẹ ọkan mi, to fi itẹ ogo rẹ silẹ o wa damilare. Iwọ nikan ṣoṣo la ma sin ni gbogbo aiye wa o, Ọba nla. Wa gaga giga, Ẹyin l'ogo yẹ. Ẹyin ni yin yẹ, Ọba awọn 'ba a yin tan Eledumare. Ibere ati opin, A wolẹ fun o. Ẹyin l'ogo yẹ, Ẹyin ni yin yẹ. [Tenor Solo & Chorus] Mee le ṣai dupẹ ore rẹ si mi Olu ọrun o. A wolẹ ṣai dupẹ ore rẹ si wa. Mee le ṣai dupẹ ore rẹ si mi Olu ọrun o. A wolẹ ṣai dupẹ ore rẹ si wa. [Verse] Ore rẹ to boju aiye, Alapinla to sọ aiyero, Ẹrujẹjẹ l'eti okun pupa. Gbanigbani l'an saya, Ẹyin Arugbo ọjọ, Ọba ko ma ti ka l'ẹyin, Ajiji ododoji. Rawo Ọmọ Mary. Ọba to lo korin kese, korin kese, korin kese. [Coda] Ah! Ẹyin l'ogo yẹ. Ibere ati opin, A wolẹ fun o. Ẹyin l'ogo yẹ, Ẹyin ni yin yẹ. Baba, Ọmọ, Ẹmi mi, Eyi ni yin yẹ.

Download the sheet music

Eyin L'ogo Ye

Eyin L'ogo Ye

By Cornelius Ogar
Solfa
Yoruba
2 pages
2 Downloads
Offertory Hymns Recessional / Dismissal Hymns Holy Trinity Hymns
0 0

More lyrics you may want