EWA SOPE FUN BABA by Jude Nnam — Lyrics

Jude Nnam Yoruba Offertory Hymns Celebrations Hymns Solfa notation

Full Lyrics

CHORUS Gba a lọwọ mi o Baba, gba a lọwọ mi o Baba Gba a lọwọ mi o Baba, gbọrẹ atinuwa mi Gbọrẹ atọkanwa mi Ti mo mu wa fun, mu wa fun ọrẹ rẹ Gba a lọwọ mi o Baba, ah gba a lọwọ mi Gba a lọwọ mi o Baba, gba a lọwọ mi o Baba VERSE 1 Baba to da mi si doni o Kabiyesi Ọba Olodumare Oluwa Baba Ọpẹ ni fun o Baba, oh Baba, Baba Iyin loyẹ fun o Kabiyesi o, Ọba ologo julọ VERSE 2 Oluwa Baba, Olodumare Ọba, gba a lọwọ mi O Jesu Kristi Ọba, gba a lọwọ mi O Baba, Baba, Baba, gba a lọwọ mi Oluwa Baba, Olodumare Ọba, gba a lọwọ mi O Jesu Kristi Ọba, gba a lọwọ mi VERSE 3 Ẹwa, ẹwa, ẹwa Ẹwa sọpẹ fun Baba, ẹyin eniyan mi, ẹwa to joju wa Ẹwa sọpẹ fun Baba mi, ẹyin eniyan mi, ẹwa to joju wa Ẹwa sọpẹ fun Baba, ẹyin eniyan mi, ẹwa to joju wa Ẹwa sọpẹ fun Baba mi, ẹyin eniyan mi, ẹwa Ẹwa sọpẹ fun Baba, ẹyin eniyan mi, ẹwa to joju wa Ẹwa sọpẹ fun Baba mi, ẹyin eniyan mi, ẹwa to joju wa, ẹwa VERSE 4 Kabiyesi, Kabiyesi Ọba Baba to da mi si doni o, Oluwa Baba Olodumare, Oluwa Baba Ọpẹ ni fun o Baba, Baba, Baba Ọpẹ ni fun o Baba, iyin loyẹ fun o Kabiyesi o, Ọba ologo julọ VERSE 5 O Baba, O Baba, O Baba, gba a lọwọ mi o Baba Oluwa Baba, Olodumare Ọba, gba a lọwọ mi O Jesu Kristi Ọba, gba a lọwọ mi O Baba, O Baba, O Baba, gba a lọwọ mi o Baba Oluwa Baba, Olodumare Ọba, gba a lọwọ mi

Download the sheet music

EWA SOPE FUN BABA

EWA SOPE FUN BABA

By Jude Nnam
Solfa
Yoruba
6 pages
0 Downloads
Offertory Hymns Celebrations Hymns
0 0

More lyrics you may want