Full Lyrics
VERSE 1
Ẹmi Ọrun jọwọ wa
Olupese ọba jọwọ O
Jẹ ki ẹmi rẹ baba iye
Ko wa ba sori gbogbo wa.
CHORUS
Iwa ẹri iwa gbogbo
Jọwọ foriji wa O Lodumare
Iwa ẹri iwa gbogbo
Jọwọ foriji wa O Lodumare
VERSE 2
Ẹmi Ọrun jọwọ wa
Olugbala wa a yin O O
Ninu 'laa sigbo pẹlu iya
Ṣe kayẹ karii gbogbo wa.
VERSE 3
Ẹmi Ọrun jọwọ wa
Olugbala Ọba jọwọ O
Jẹ ki itunu rẹ baba iye
Ko wa ba sori gbogbo wa.
VERSE 4
Ẹmi Ọrun jọwọ wa
Olupese Ọba jọwọ O
Jẹ ki imọlẹ rẹ baba iye
Ko wa tan sinu gbogbo wa.