ẸLU AGOGO KERESIMESI by Jude Nwankwo — Lyrics

Jude Nwankwo Yoruba Christmas Hymns Solfa notation

Full Lyrics

Ẹlu agogo, ẹlu agogo, ẹlu agogo. Ẹlu agogo. Ẹlu agogo, Ẹlu agogo, ẹlu agogo Keresimesi, Ẹlu agogo. Ah, ah, ah, Ẹlu agogo, Olugbala de o, ẹlu agogo. Ẹlu soke, ẹlu agogo, Ẹlu agogo Keresimesi, ẹlu agogo Keresimesi, Ẹlu soke, ẹlu agogo. Ah, ah, ah, Ẹlu agogo Olugbala de o, ẹlu agogo. Ẹlu soke. Awọn 'luṣọ aguntan, wọn sọ ẹran wọn, Imọlẹ yi wọn ka, Ooo, wọn ni 'ki lode o?' Aṣẹ Olugbala la bi, Olugbala wa, Kabọ. Ẹlu soke, ẹlu agogo, ẹlu agogo, Ẹlu agogo Keresimesi, ẹlu soke. Ẹlu agogo. Ah, ah, ah, Ẹlu agogo Olugbala de o, ẹlu agogo. Irawọ kan yọ loju ọrun. Ah, irawọ, ah, Irawọ run si awọn Ọba mẹta, awọn angeli nkọrin loke O p'Olugbala wa ti de, Olugbala wa Kabọ. A fọpẹ fun Baba, A fọpẹ fun Ọmọ, A fọpẹ fun Ẹmi Mimọ o. Ẹmi Mimọ p'Olugbala wa ti de, Olugbala wa Kabọ. Ẹlu agogo, ẹlu agogo, ẹlu agogo, Ẹlu agogo, ẹlu agogo, ẹlu agogo, ẹlu agogo. Ẹlu soke, ẹlu agogo, ẹlu agogo, Ẹlu agogo Keresimesi, ẹlu agogo. Ah, ah, ah, Ẹlu agogo Olugbala de o, ẹlu agogo. Kabọ Jesu, kabọ. Ẹlu agogo Olugbala de o, ẹlu agogo. Kabọ Jesu, kabọ. Ẹlu agogo Olugbala de o, ẹlu agogo. Kabọ Jesu, kabọ. Ẹlu agogo Olugbala de, ẹlu agogo. Ẹlu agogo Keresimesi.

Download the sheet music

ẸLU AGOGO KERESIMESI

ẸLU AGOGO KERESIMESI

By Jude Nwankwo
Solfa
Yoruba
3 pages
10 Downloads
Christmas Hymns
0 0

More lyrics you may want