E JE KA JO YO by David Aina — Lyrics

David Aina Yoruba English Christmas Hymns Solfa notation

Full Lyrics

CHORUS Ẹ jẹ ka jọ yọ ka fi jo si o, A bi Olugbala kan fun wa, Ẹ yin O ni gbogbo ẹ ho ẹ yọ A bi Jesu, Olugbala. CHORUS (English) Let us now rejoice and hail this great morn; For the world a mighty Saviour's born; Glorious King, for ever be Thou adored, Holy Jesus, redeemer Lord! REFRAIN A wa ki O, a wa ki Ọba mimọ, A wa juba fun O, Ọba Ogo, Ẹ yin O ni gbagbọ ẹ ho ẹ yọ A bi Jesu, Olugbala. REFRAIN (English) We salute Thee new born, holy King! Pray, accept the loyal tribute we bring; Glorious King for ever be Thou adored Blessed Jesus, our Saviour Lord! VERSE 1 Ijọba yoo wa ni ejika rẹ, Oun ni Ọba awọn Ọba, Oun yoo jọba titi aye o Alade alafia. VERSE 1 (English) King of kings is He, and Lord of Lords, Ever will He reign Prince of peace, On His shoulder will the government be; And His Kingdom will never cease! VERSE 2 Awọn amoye mẹta igbani, wọn ri irawọ kan didan, Irawọ yii ni wọn tọ lẹhin, lati juba fun Ọba tuntun wọn wa pe fun. VERSE 2 (English) Three wise men came from a land so far, Guided by a bright shining star, In a manger the baby they saw; To Him they gave all the gifts they bore praising Him.

Download the sheet music

E JE KA JO YO

E JE KA JO YO

By David Aina
Solfa
Yoruba, English
1 page
2 Downloads
Christmas Hymns
0 0

More lyrics you may want