Egan mi ko ye o by A. O. Adeogun (arr. Jude Nwankwo) — Lyrics

A. O. Adeogun (arr. Jude Nwankwo) Yoruba Folk songs Prayer Hymns Solfa notation

Full Lyrics

Ẹgan mi ko yẹ o, ọta mi ma yọ mi o, ọta mi ma yọ mi o, O ma yọ mi o. Ti mo ba ṣubu, ti mo ba ṣubu, Oluwa mbẹ lati gbe mi dide. Ẹgan mi ko yẹ o, ọta mi ma yọ mi o, ọta mi ma yọ mi o, O ma yọ mi o. Ti mo ba ṣubu, ti mo ba ṣubu, Oluwa mbẹ lati gbe mi dide. Ẹgan mi ko yẹ o. Rara ko yẹ mi, ẹgan mi ko yẹ o. Ẹgan mi ko yẹ o, ẹgan mi ko yẹ o rara. Ẹgan mi, ẹgan mi ko yẹ o. Oluwa mbẹ, Oluwa mbẹ. Ẹgan mi, ọta mi ma yọ mi o, Ọta mi ma yọ mi o. Ti mo ba ṣubu, ti mo ba ṣubu, Oluwa mbẹ lati gbe mi dide. Oluwa mbẹ lati gbe mi dide. Oluwa mbẹ lati gbe mi dide.

Download the sheet music

Egan mi ko ye o

Egan mi ko ye o

By A. O. Adeogun (arr. Ju...
Solfa
Yoruba
4 pages
1 Downloads
Folk songs Prayer Hymns
0 0

More lyrics you may want