Full Lyrics
CHORUS
Gb'ọrẹ wa o, gb'ọrẹ wa o, Eledumare,
A wa s'ọpẹ fun ore ọfẹ rẹ ninu aiye wa, Baba adupẹ o.
Gb'ọrẹ ti a mu wa, Eledumare.
VERSE 1
Ọpẹ iyin, ogo l'a mu wa si'waju rẹ,
Baba ijọ ilu a t'orin l'a mu wa si'waju rẹ.
Baba l'oke, Baba l'oke,
Tẹwọ gb'ọpẹ, tẹwọ gb'ọpẹ wa.
Baba l'oke, Baba l'oke,
Gb'ọrẹ ti a mu wa, Eledumare.
VERSE 2
O sọ fun wa wipe ninu ohun k'ohun ki a ma dupẹ,
Ohun ti ba ṣẹlẹ aṣiṣe pọ fun rere fun wa.
Adupẹ adupẹ, Baba adupẹ o,
Gb'ọrẹ ti a mu wa, Eledumare.
VERSE 3
Mo mọ riri ore Baba o,
Iwọ ọrẹ mi ye o.
Sunmọ bi wa gbọ jare,
Sunmọ bi wa gbọ Baba, ṣere rẹ fun wa.
Sunmọ bi wa gbọ Baba, ṣere rẹ fun wa.
Sunmọ bi wa gbọ Baba, ṣere rẹ fun wa.
Baba wa, a wa dupẹ.