Full Lyrics
REFRAIN
Baba Onibuọrẹ
Awimayẹhun
Iwọ l'a wa rubọ si
Gb'ọrẹ wa gb'ẹbọ wa
Ẹbọ to ju ẹbọ ni o
Ẹbọ Oluwa wa ni
Iye ẹbọ pipe ẹbọ iye ẹbọ
O Iwọ l'a wa rubọ si
Gb'ọrẹ wa gb'ẹbọ wa o!
VERSE 1
Baba l'ọrun a tun de
A wa rubọ si o
Akara yi la mu wa
Ọti yi la mu wa
Tẹwọ gba ọrẹ wa
Tẹwọ gba ẹbọ wa
Ye dakun yiju si wa Baba
VERSE 2
Ọba mi mọ a dupẹ
Ọpẹ lo yẹ o Baba
Awimayẹhun ẹ ṣe
Aṣẹkan maku ẹ ṣe
Jọwọ wa gb'ọrẹ wa
Jọwọ wa gb'ẹbọ wa
Ye dakun yiju si wa Baba