Full Lyrics
Baba mimo a de,
awa siwaju re.
Baba mimo a de,
a m'ope wa 'le fun O.
Baba mimo a de,
a tun wa ju'ba re,
e lari ese wa ji.
Wa, gba adura wa, Baba.
Ran Emi mimo re si wa,
ki bukun re Oluwa.
Baba mimo, gbadura wa,
wa f'ase si Baba.
Mo f'ase si Baba mimo,
k'adura wa gba l'oruko Jesu.
Amin o.