Full Lyrics
VERSE 1
Baba ye, jẹ ki 'jọba rẹ de.
CHORUS
Baba ye, jẹ ki 'jọba rẹ bọ,
K'aṣẹ rẹ bẹrẹ lori wa,
K'aṣẹ rẹ bẹrẹ lori wa,
K'aṣẹ rẹ bẹrẹ lori wa,
K'aṣẹ rẹ bẹrẹ lori wa.
VERSE 2
Baba ye, jẹ ki ifẹ rẹ de.
VERSE 3
Baba ye, jẹ ki ogo rẹ de.
CODA
Baba ye, jẹ ki 'jọba rẹ de,
S'aiye wa.