Full Lyrics
CHORUS
Gb'ọpẹ wa o, gb'ọpẹ wa o
Baba L'oke gb'ọpẹ wa
Ẹlẹduwa gb'ọpẹ wa
Fun ore ọfẹ rẹ ninu aiye wa
Baba adupẹ, wa o Baba
Gb'ọpẹ ti a mu wa Eledumare
VERSE 1
Ọpẹ l'a mu wa, ọpẹ l'a mu wa Baba
Ijo ti a f'orin l'a mu wa
Ijo ti a f'ilu l'a mu wa
Baba L'oke, tẹwọ gb'ọpẹ wa
Baba L'oke, tẹwọ gb'ọpẹ wa
Gb'ọpẹ ti a mu wa Eledumare
VERSE 2
O ṣe fun wa wipe ninu ohun kohun
Ki a ma dupẹ ohun ti ba ṣẹlẹ o si ṣe
Pe fun rere fun wa
Adupẹ, Baba adupẹ o
Gb'ọrẹ ti a mu wa Eledumare
VERSE 3
Iwọ mo ri, iwọ mo ri
Iwọ Baba iwọ nikan ṣoṣo ni
Sunmọ 'bi wa gba o jare
Sunmọ 'bi wa gba, Baba ṣ'ere rẹ fun wa
Sunmọ 'bi wa gba, sunmọ 'bi wa gba
Ṣ'ere rẹ fun wa, sunmọ 'bi wa gba
Baba ṣ'ere rẹ fun wa, sunmọ 'bi wa gba
O ṣe fun wa, awa dupẹ, awa dupẹ