Full Lyrics
Awa dupẹ o Eledumare Baba, ẹṣe o adupẹ.
Awa dupẹ Baba, awa dupẹ ẹṣe, adupẹ Baba ẹṣe, awa dupẹ.
Ẹṣe adupẹ Baba, Baba gbọpẹ wa adupẹ, awa dupẹ adupẹ Baba, Ọba awọn ọba o.
Ọba awọn ọba o, Baba bawo l'ẹṣe tobi to, ẹṣe ẹṣe ẹṣe Eledumare, Kabiyesi Ọba kibiyesi.
Maa gbe ga, maa gbe ga, ẹṣe o adupẹ, ẹṣe adupẹ ẹṣe, Kabiyesi Ọba o adupẹ ẹ ṣe, Awa dupẹ.
Atọbanjaiye o, Atọbanjaiye o Baba adupẹ, kini maa fi san fun Ọ Baba.
Eledumare maa gbe ga o maa kọrin, Kabiyesi Ọba mimọ o.
Ninu ipọnju O'n kọ mi yọ, Ara ile Ara ẹyọ, ẹ dide k'adupẹ l'ọwọ Ọlọrun nitori ore to ṣe laiye wa o pọ gaan.
Maa gbe ga, maa gbe ga o maa kọrin o maa gbe ga, adupẹ Baba, awa dupẹ Baba.