Full Lyrics
REFRAIN
Baba wa, a de o! Baba wa, a de o!
A de, a wa yin ọ o, a de, a wa yin ọ o.
Awimayẹhun! Baba wa, a de o!
Alewileṣe o! Baba wa, a de o!
A de, a wa yin ọ o, a de, a wa yin ọ o.
Oyigiyigi o! Baba wa, a de o!
VERSE 1
Baba feti si wa,
K'o ma ta wa danu.
Akigbe si Baba o!
Awa ma de o!
VERSE 2
Baba wa dakun,
Baba foriji wa.
Wa fun wa ni joko,
Awa ma de o!
VERSE 3
Baba wa, Oloore,
Oluwa ye jọwọ.
Fun wa ni 'fọkansi,
Awa ma de o!
VERSE 4
Baba wa mi si wa!
Oluwa o!
Baba Olodumare!
Awa ma de o!